Ojú oró ló n l'ékè omi, òsíbàtà ló n l'ékè odò. Ma gbẹ̀yìn, ma gbẹ̀yin l'agba ilédì n dún! Gbogbo wa la máa l'ékè ọ̀tá, r'ẹ́yìn odì! A máa l'ékè abínú